JSS1 YORUBA LANGUAGE L2 SECOND TERM CAT 2
TIME: 40 minutes
INSTRUCTION: Answer all questions in Sections A and B.
SECTION A: OBJECTIVE TEST
NO. OF QUESTIONS: 20
SPECIFIC INSTRUCTION: Select the correct answer from the options a – d.
- Eni ti o ko ewi mura si ise ore mi ni: “Mura si ise”. (a) Faleti (b) Opadotun (c) J.F.Odunjo (c) Wole Soyinka
- Ohun ti o n je ki eniyan di eni giga ni (a) ole (b) ore (c) ise (d) iwa
- Eko ti a ri ko ninu ewi “mura si ise” ni ……….. (a) ki a ma se jale (b) imototo (c) ki a ni ife (d) ki a mura sise.
- Kin ni itumo oro yii “raago”. (a) Lowo (b) saisan (c) tosi (d) sun
- Pari ewi yii: Bi a ko ba reni gbekele, a ……….. (a) sun (b) sere (c) tera mose eni (d) a maa n jo
- Oro- ise ti o wa ninu “Sola wo aso ”ni ……….. (a) Sola (b) wo (c) aso (d) ra
- Toka si oro aponle ninu gbolohun yii “Ade sanra ropoto” (a) Ade (b) sanra (c) ropoto (d) gan
- Toka si oro apejuwe ninu gbolohun yii “Maluu dudu sun” (a) maluu (b) dudu (c) sun (d) je
- Isori oro wo ni o je opomulero ninu gbolohun?