JSS1 YORUBA LANGUAGE L2 SECOND TERM CAT 1

TIME: 40 minutes

INSTRUCTION: Answer all questions in Sections A and B.

 

SECTION A: OBJECTIVE TEST

NO. OF QUESTIONS: 20

SPECIFIC INSTRUCTION: Select the correct answer from the options a – d.

  1. Ohun ti a n pe ni silebu ni …………. (a) oro pupo (b) oro kukuru (c) ege oro (d) oro asopo
  2. Silebu meloo ni o wa ninu oro yii, ‘olopaa’? (police) (a) meji (b) meta (c) merin (d) marun
  3. Silebu meloo ni o wa ninu oro yii, ‘maluu’? (cow) (a) meji (b) meta (c) merin (d) eyo kan
  4. Ami ohun meloo lo wa lori oro yii, ‘olopaa’? (police) (a) meji (b) meta (c) merin (d) marun
  5. Ami ohun meloo lo wa lori oro yii, ‘maluu’? (cow) (a) meji (b) meta (c) merin (d) marun
  6. Ninu iyara ikawe ni a ti maa n ri eleyii (a) elede (b) adire (c) patako ikowe (d)eja
  7. Oruko ti awon Yoruba n pe ‘teacher’ ni …………. (a) akeko (b) oga ile iwe (c) oluko (d) omo ile iwe
  8. Oruko ti awon Yoruba n pe ‘Chalk’ ni ………….

Back to: JSS1 Yoruba Language L2 Continuous Assessment Tests and Examinations > Second Term Assessments
© [2022] Spidaworks Digital - All rights reserved.
error: Alert: Content is protected !!